Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

in #nigeria5 years ago

Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .

Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.


Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni awon efo soko ti a gbin si orí oko wa. Won tutu minijojo, beni won si tun dun wo lati ara awo ti won muwa. Soko je ikan lara awon efo ti awon eniyan ma n du lati ri pupo. Idi ni wipe o dun ni jije, beni osi tun kun fun opolopo eroja ti o n se ara loore.


Lenovo_A1000_IMG_20180827_094215.jpg


Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .

Coin Marketplace

STEEM 0.25
TRX 0.11
JST 0.031
BTC 62166.63
ETH 3021.89
USDT 1.00
SBD 3.72