Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

in #nigeria5 years ago

Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .

Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.

Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni eso tomato ti a jere ni orí oko wa ni aipeyii . Ni iwonba ni onka nti ari, idi si ni wipe, idanwo lati wo bi yo se wu si ni a fi se. Nitori na, ile kekere la gbin won si.


Lenovo_A1000_IMG_20180903_094541.jpg


Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .

Sort:  

Congratulations @factism! You have completed the following achievement on the Steem blockchain and have been rewarded with new badge(s) :

You published more than 550 posts. Your next target is to reach 600 posts.

You can view your badges on your Steem Board and compare to others on the Steem Ranking
If you no longer want to receive notifications, reply to this comment with the word STOP

To support your work, I also upvoted your post!

Vote for @Steemitboard as a witness to get one more award and increased upvotes!

Coin Marketplace

STEEM 0.25
TRX 0.11
JST 0.033
BTC 62379.78
ETH 3034.69
USDT 1.00
SBD 3.78