Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

in #nigeria5 years ago

Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .

Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.

Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni awon eso Cashew orí oko wa . Edinwo ni ata fun awon agbe ti won nifesi.


Lenovo_A1000_IMG_20180904_092826.jpg


Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .

Coin Marketplace

STEEM 0.29
TRX 0.12
JST 0.033
BTC 63071.06
ETH 3121.31
USDT 1.00
SBD 3.84