Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

in #wafrica5 years ago

Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .

Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.

Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni igi eso raddish orí oko wa. A n gbero lati tun gbin ni odun ti a wa yii.


IMG_20190103_143907_584.jpg


Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .

Coin Marketplace

STEEM 0.30
TRX 0.12
JST 0.033
BTC 64093.86
ETH 3123.80
USDT 1.00
SBD 3.94