Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

in #wafrica5 years ago (edited)

Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .

Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.

Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni awon apo ti a ti pese sile fun gbigbin eso cashew ni ori oko wa .A n lero lati gbin bi egberun meji ni odun yi


IMG_20190211_102613.jpg


Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .

Coin Marketplace

STEEM 0.27
TRX 0.12
JST 0.032
BTC 57369.97
ETH 2943.81
USDT 1.00
SBD 3.63